GOD artwork

Song

GOD

Seyi Vibez

2026 · African

No ratings yet

GOD Lyrics

by Seyi Vibez

Hola (It's Zee on the beat) Oluwaloseyi oh-oh Vibez Zee on the beatin' Ooh-yeah, yeah-yeah Pikin wey no get helper suppose to get sense oh T'ọ bá tẹ ẹ mọ'lẹ', tún sọ fún wọn pé brother, no vex oh 'Cause some people dey, dem be enemies of progress oh Mama call me yesterday, 'ku ọjọ' mẹ'ta, she say hello But as young as I am, I get guys wey dey blao Show me your friend, I'll tell you who you are If you give dem the chance, dem go do you anyhow Maree paddie ẹ jẹ, s'ọ mọ pé kódà oh? But as I be street boy, e no mean say mí ò ní'wá rárá Ṣé b'owó tó ṣé Kíṣì ṣá, l'ọmọpẹ ń wá, ayy Ẹyín to láyé, ẹ dúró tìmí K'alàánú mí, k'òwá mi rí Ọfà ayé, májẹ kò bá mí So, I dey pray Almighty Ẹyín to láyé, ẹ dúró tì mí K'alàánú mí, k'òwá mi rí Ọfà ayé, májẹ kò bá mí So, I dey pray, Almighty Àwa dé, dé-dé, ayy-ayy, àwa dé Mo ti dé sí ẹ lọ́rùn, Bàbá, mo tí dé, ayy-yy Àwa dé, dé-dé, ayy-ayy, àwa dé Àti dé sí ẹ lọ́rùn, Bàbá, àwa dé, ah-ah, yeah-yeah Ojú ló mọ ń t'oyo 'nú Talika mo òun t'obá tàn Olówó mọ'ye ìwọ'n tó wọn K'Ọlọhun mà bá irè ayọ' mí jé No rich papa and no rich mama Sometimes, I wonder, why I come this life? Maybe na me God sent to make things right For my family with my melody I can hear them screamin' my name Olúwaloṣeyi, dem-a feeling the wave I can picture the face Them draggin' my cloth, and them sayin', "Ooh-yeah" I no wan sing in vain Make bad belle no go ask say wetin I gain? Bàbá, gbé mì l'ọ'wọ' s'ókè, ayy Yeah, ooh-yeah Ẹyín to láyé, ẹ dúró tìmí K'alàánú mí, k'òwá mi rí Ọfà ayé, májẹ kò bá mí So, I dey pray Almighty Ẹyín to láyé, ẹ dúró tì mí K'alàánú mí, k'òwá mi rí Ọfà ayé, májẹ kò bá mí So, I dey pray, Almighty Àwa dé, dé-dé, ayy-ayy, àwa dé Mo ti dé sí ẹ lọ́rùn, Bàbá, mo tí dé, ayy-yy Àwa dé, dé-dé, ayy-ayy, àwa dé Àti dé sí ẹ lọ́rùn, Bàbá, àwa dé, ah-ah, yeah-yeah Ẹyín to láyé, ẹ dúró tìmí K'alàánú mí, k'òwá mi rí Ọfà ayé, májẹ kò bá mí So, I dey pray, Almighty Ẹyín to láyé, ẹ dúró tì mí K'alàánú mí, k'òwá mi rí Ọfà ayé, májẹ kò bá mí So, I dey pray, Almighty Àwa dé, dé-dé, ayy-ayy, àwa dé (dé, dé) Mo ti dé sí ẹ lọ́rùn, Bàbá, mo tí dé, ayy-yy (mo tí dé o) Àwa dé, dé-dé, ayy-ayy, àwa dé Àti dé sí ẹ lọ́rùn, Bàbá, àwa dé, ah-ah, yeah-yeah Àwa dé, ayy-ayy Mo ti dé (Zee on the Mix) Vibe Boy

Lyrics are provided for educational, critique, and study purposes under fair use. Sourced via LRCLIB. If you are the copyright owner and wish to request removal, please visit our DMCA & Copyright Policy.

Rate this song

Log in to rate and review this song.

No written reviews yet.